ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 27:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nígbà tí àwọn ẹ̀ka igi rẹ̀ bá ti gbẹ,

      Àwọn obìnrin máa wá ṣẹ́ wọn,

      Wọ́n á sì fi dáná.

      Torí àwọn èèyàn yìí ò ní òye.+

      Ìdí nìyẹn tí Aṣẹ̀dá wọn ò fi ní ṣàánú wọn rárá,

      Ẹni tó dá wọn ò sì ní ṣojúure kankan sí wọn.+

  • Jeremáyà 8:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Kódà ẹyẹ àkọ̀ tó ń fò lójú ọ̀run mọ àkókò rẹ̀;*

      Oriri àti ẹyẹ olófèéèré àti ẹ̀gà* kì í yẹ àkókò tí wọ́n máa pa dà.*

      Àmọ́ àwọn èèyàn mi ò mọ ìdájọ́ Jèhófà.”’+

  • Hósíà 4:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 A ó pa àwọn èèyàn mi lẹ́nu mọ́,* torí pé wọn kò ní ìmọ̀.

      Nítorí pé wọ́n ti kọ̀ láti mọ̀ mí,+

      Èmi náà á kọ̀ wọ́n pé kí wọ́n má ṣe àlùfáà mi mọ́;

      Àti nítorí pé wọ́n gbàgbé òfin* Ọlọ́run wọn,+

      Èmi náà á gbàgbé àwọn ọmọ wọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́