Émọ́sì 5:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Gbé ariwo orin rẹ kúrò lọ́dọ̀ mi;Má sì jẹ́ kí n gbọ́ ìró ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín rẹ.+ 24 Jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo ṣàn wálẹ̀ bí omi,+Àti òdodo bí odò tó ń ṣàn nígbà gbogbo.
23 Gbé ariwo orin rẹ kúrò lọ́dọ̀ mi;Má sì jẹ́ kí n gbọ́ ìró ohun ìkọrin olókùn tín-ín-rín rẹ.+ 24 Jẹ́ kí ìdájọ́ òdodo ṣàn wálẹ̀ bí omi,+Àti òdodo bí odò tó ń ṣàn nígbà gbogbo.