Àìsáyà 57:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 “Àmọ́ àwọn ẹni burúkú dà bí òkun tó ń ru, tí kò lè rọ̀ wọ̀ọ̀,Omi rẹ̀ sì ń ta koríko inú òkun àti ẹrẹ̀ sókè. 21 Kò sí àlàáfíà fún ẹni burúkú,”+ ni Ọlọ́run mi wí.
20 “Àmọ́ àwọn ẹni burúkú dà bí òkun tó ń ru, tí kò lè rọ̀ wọ̀ọ̀,Omi rẹ̀ sì ń ta koríko inú òkun àti ẹrẹ̀ sókè. 21 Kò sí àlàáfíà fún ẹni burúkú,”+ ni Ọlọ́run mi wí.