Àìsáyà 56:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, ẹni tó ń kó àwọn tó fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ,+ kéde pé: “Màá kó àwọn míì jọ sọ́dọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ sí àwọn tí a ti kó jọ tẹ́lẹ̀.”+
8 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, ẹni tó ń kó àwọn tó fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ,+ kéde pé: “Màá kó àwọn míì jọ sọ́dọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ sí àwọn tí a ti kó jọ tẹ́lẹ̀.”+