ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Òwe 17:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ẹni tó bá dá ẹni burúkú láre àti ẹni tó dá olódodo lẹ́bi+

      Àwọn méjèèjì jẹ́ ẹni ìkórìíra lójú Jèhófà.

  • Málákì 2:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “Ẹ ti jẹ́ kí ọ̀rọ̀ yín sú Jèhófà.+ Àmọ́ ẹ̀ ń sọ pé, ‘Kí la ṣe tó jẹ́ kí ọ̀rọ̀ wa sú u?’ Torí bí ẹ ṣe ń sọ pé, ‘Gbogbo ẹni tó ń ṣe ohun búburú jẹ́ ẹni rere lójú Jèhófà, inú rẹ̀ sì dùn sí wọn,’+ tàbí bí ẹ ṣe ń sọ pé, ‘Ibo ni Ọlọ́run tó ń ṣe ìdájọ́ òdodo wà?’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́