-
Míkà 7:16, 17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Àwọn orílẹ̀-èdè yóò rí i, ojú sì máa tì wọ́n bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n lágbára.+
Wọ́n á fi ọwọ́ bo ẹnu;
Etí wọn á di.
17 Wọ́n á lá erùpẹ̀ bí ejò;+
Wọ́n á máa gbọ̀n rìrì bí wọ́n ṣe ń jáde látinú ibi ààbò wọn bí àwọn ẹran tó ń fàyà fà.
Wọ́n á wá sọ́dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run wa pẹ̀lú ìbẹ̀rù,
Ẹ̀rù rẹ yóò sì bà wọ́n.”+
-