Àìsáyà 41:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Má bẹ̀rù, ìwọ Jékọ́bù kòkòrò mùkúlú,*+Ẹ̀yin ọkùnrin Ísírẹ́lì, màá ràn yín lọ́wọ́,” ni Jèhófà, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì wí. Àìsáyà 48:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà! Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+ Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+ Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+
14 Má bẹ̀rù, ìwọ Jékọ́bù kòkòrò mùkúlú,*+Ẹ̀yin ọkùnrin Ísírẹ́lì, màá ràn yín lọ́wọ́,” ni Jèhófà, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì wí.
20 Ẹ jáde kúrò ní Bábílónì!+Ẹ sá kúrò lọ́dọ̀ àwọn ará Kálídíà! Ẹ fi igbe ayọ̀ polongo rẹ̀! Ẹ kéde rẹ̀!+ Ẹ jẹ́ kó di mímọ̀ dé àwọn ìkángun ayé.+ Ẹ sọ pé: “Jèhófà ti tún Jékọ́bù ìránṣẹ́ rẹ̀ rà.+