Jòhánù 7:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹnu ya àwọn Júù, wọ́n sọ pé: “Báwo ni ọkùnrin yìí ṣe mọ Ìwé Mímọ́*+ tó báyìí láìjẹ́ pé ó lọ sáwọn ilé ẹ̀kọ́?”*+ Jòhánù 7:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Àwọn òṣìṣẹ́ náà fèsì pé: “Èèyàn kankan ò sọ̀rọ̀ báyìí rí.”+
15 Ẹnu ya àwọn Júù, wọ́n sọ pé: “Báwo ni ọkùnrin yìí ṣe mọ Ìwé Mímọ́*+ tó báyìí láìjẹ́ pé ó lọ sáwọn ilé ẹ̀kọ́?”*+