Jẹ́nẹ́sísì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà Ọlọ́run wá gbin ọgbà kan sí Édẹ́nì,+ ní apá ìlà oòrùn; ó sì fi ọkùnrin tó dá+ síbẹ̀.