Àìsáyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+ Àìsáyà 56:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 56 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ máa ṣe ìdájọ́ òdodo,+ kí ẹ sì máa ṣe òdodo,Torí ìgbàlà mi máa tó dé,A sì máa ṣí òdodo mi payá.+
2 Wò ó! Ọlọ́run ni ìgbàlà mi.+ Màá gbẹ́kẹ̀ lé e, ẹ̀rù ò sì ní bà mí;+Torí Jáà* Jèhófà ni okun mi àti agbára mi,Ó sì ti wá di ìgbàlà mi.”+
56 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ máa ṣe ìdájọ́ òdodo,+ kí ẹ sì máa ṣe òdodo,Torí ìgbàlà mi máa tó dé,A sì máa ṣí òdodo mi payá.+