1 Sámúẹ́lì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà yóò fọ́ àwọn tó ń bá a jà sí wẹ́wẹ́;*+Yóò sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run.+ Jèhófà yóò ṣe ìdájọ́ títí dé gbogbo ìkángun ayé,+Yóò fún ọba rẹ̀ ní agbára+Yóò sì gbé ìwo* ẹni àmì òróró rẹ̀ ga.”+ Àìsáyà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó máa ṣe ìdájọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,Ó sì máa yanjú ọ̀rọ̀* láàárín ọ̀pọ̀ èèyàn. Wọ́n máa fi idà wọn rọ ohun ìtúlẹ̀,Wọ́n sì máa fi ọ̀kọ̀ wọn rọ ohun ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn.+ Àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́,Wọn ò sì ní kọ́ṣẹ́ ogun mọ́.+
10 Jèhófà yóò fọ́ àwọn tó ń bá a jà sí wẹ́wẹ́;*+Yóò sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run.+ Jèhófà yóò ṣe ìdájọ́ títí dé gbogbo ìkángun ayé,+Yóò fún ọba rẹ̀ ní agbára+Yóò sì gbé ìwo* ẹni àmì òróró rẹ̀ ga.”+
4 Ó máa ṣe ìdájọ́ láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,Ó sì máa yanjú ọ̀rọ̀* láàárín ọ̀pọ̀ èèyàn. Wọ́n máa fi idà wọn rọ ohun ìtúlẹ̀,Wọ́n sì máa fi ọ̀kọ̀ wọn rọ ohun ìrẹ́wọ́ ọ̀gbìn.+ Àwọn orílẹ̀-èdè kò ní yọ idà sí ara wọn mọ́,Wọn ò sì ní kọ́ṣẹ́ ogun mọ́.+