Àìsáyà 49:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+ Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+ Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+ Àìsáyà 66:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí ìyá ṣe ń tu ọmọ rẹ̀ nínú,Bẹ́ẹ̀ ni màá máa tù yín nínú;+Ẹ sì máa rí ìtùnú torí Jerúsálẹ́mù.+
13 Ẹ kígbe ayọ̀, ẹ̀yin ọ̀run, sì máa yọ̀, ìwọ ayé.+ Kí inú àwọn òkè dùn, kí wọ́n sì kígbe ayọ̀.+ Torí Jèhófà ti tu àwọn èèyàn rẹ̀ nínú,+Ó sì ń ṣàánú àwọn èèyàn rẹ̀ tí ìyà ń jẹ.+