ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 35:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ọ̀nà kan sì máa wà níbẹ̀,+

      Àní, ọ̀nà tí à ń pè ní Ọ̀nà Ìjẹ́mímọ́.

      Aláìmọ́ kò ní gba ibẹ̀ kọjá.+

      Àwọn tó ń rìn lójú ọ̀nà ló wà fún;

      Òmùgọ̀ kankan ò sì ní rìn gbéregbère lọ síbẹ̀.

  • Àìsáyà 60:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Gbogbo èèyàn rẹ máa jẹ́ olódodo;

      Ilẹ̀ náà máa di tiwọn títí láé.

      Àwọn ni èéhù ohun tí mo gbìn,

      Iṣẹ́ ọwọ́ mi,+ ká lè ṣe mí lọ́ṣọ̀ọ́.+

  • Ìfihàn 21:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Àmọ́ ohunkóhun tó ní àbààwọ́n àti ẹnikẹ́ni tó ń hùwà tó ń ríni lára, tó sì ń tanni jẹ kò ní wọnú rẹ̀ rárá;+ àwọn tí a kọ orúkọ wọn sínú àkájọ ìwé ìyè Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà nìkan ló máa wọnú rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́