Àìsáyà 50:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀+ ìyá yín tí mo lé lọ dà? Àbí èwo nínú àwọn tí mo jẹ ní gbèsè ni mo tà yín fún? Ẹ wò ó! Torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín+ ni mo ṣe tà yín,Mo sì lé ìyá yín lọ torí àwọn àṣìṣe yín.+
50 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ìwé ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀+ ìyá yín tí mo lé lọ dà? Àbí èwo nínú àwọn tí mo jẹ ní gbèsè ni mo tà yín fún? Ẹ wò ó! Torí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ yín+ ni mo ṣe tà yín,Mo sì lé ìyá yín lọ torí àwọn àṣìṣe yín.+