Àìsáyà 45:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Mo ti gbé ẹnì kan dìde nínú òdodo,+Màá sì mú kí gbogbo ọ̀nà rẹ̀ tọ́. Òun ló máa kọ́ ìlú mi,+Tó sì máa dá àwọn ìgbèkùn mi sílẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́ + tàbí láìgba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.
13 “Mo ti gbé ẹnì kan dìde nínú òdodo,+Màá sì mú kí gbogbo ọ̀nà rẹ̀ tọ́. Òun ló máa kọ́ ìlú mi,+Tó sì máa dá àwọn ìgbèkùn mi sílẹ̀ lọ́fẹ̀ẹ́ + tàbí láìgba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,”+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.