-
Ìsíkíẹ́lì 20:44Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
44 Ẹ ó sì wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà nígbà tí mo bá dojú ìjà kọ yín nítorí orúkọ mi,+ kì í ṣe nítorí ìwà búburú yín tàbí ìwà ìbàjẹ́ yín, ìwọ ilé Ísírẹ́lì,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
-