-
Diutarónómì 28:33Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
33 Àwọn èèyàn tí o kò mọ̀+ ló máa jẹ èso ilẹ̀ rẹ àti gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ rẹ. Wọ́n á máa lù ọ́ ní jìbìtì, wọ́n á sì máa rẹ̀ ọ́ wálẹ̀ nígbà gbogbo.
-
-
Diutarónómì 28:63Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
63 “Bí inú Jèhófà ṣe dùn nígbà kan láti mú kí nǹkan máa lọ dáadáa fún yín, kí ẹ sì pọ̀ rẹpẹtẹ, bẹ́ẹ̀ náà ni inú Jèhófà ṣe máa dùn láti pa yín run kó sì pa yín rẹ́; ẹ sì máa pa run kúrò ní ilẹ̀ tí ẹ fẹ́ lọ gbà.
-