Jeremáyà 4:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Mo rí ilẹ̀ náà, sì wò ó! ó ṣófo, ó sì dahoro.+ Mo bojú wo ọ̀run, ìmọ́lẹ̀ wọn kò sì sí mọ́.+