Máàkù 15:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Bákan náà, wọ́n kan àwọn olè méjì mọ́gi lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ọ̀kan ní ọ̀tún rẹ̀ àti ọ̀kan ní òsì rẹ̀.+ Lúùkù 22:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Torí mò ń sọ fún yín pé ohun tó wà ní àkọsílẹ̀ ni wọ́n gbọ́dọ̀ ṣe sí mi délẹ̀délẹ̀, pé, ‘A kà á mọ́ àwọn arúfin.’+ Torí èyí ń ṣẹ sí mi lára.”+ Lúùkù 23:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Wọ́n tún ń mú àwọn ọkùnrin méjì míì tí wọ́n jẹ́ ọ̀daràn lọ, kí wọ́n lè pa wọ́n pẹ̀lú rẹ̀.+ 33 Nígbà tí wọ́n dé ibi tí wọ́n ń pè ní Agbárí,+ wọ́n kàn án mọ́gi níbẹ̀, àwọn ọ̀daràn náà sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ọ̀kan ní ọ̀tún rẹ̀ àti ọ̀kan ní òsì rẹ̀.+
37 Torí mò ń sọ fún yín pé ohun tó wà ní àkọsílẹ̀ ni wọ́n gbọ́dọ̀ ṣe sí mi délẹ̀délẹ̀, pé, ‘A kà á mọ́ àwọn arúfin.’+ Torí èyí ń ṣẹ sí mi lára.”+
32 Wọ́n tún ń mú àwọn ọkùnrin méjì míì tí wọ́n jẹ́ ọ̀daràn lọ, kí wọ́n lè pa wọ́n pẹ̀lú rẹ̀.+ 33 Nígbà tí wọ́n dé ibi tí wọ́n ń pè ní Agbárí,+ wọ́n kàn án mọ́gi níbẹ̀, àwọn ọ̀daràn náà sì wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ọ̀kan ní ọ̀tún rẹ̀ àti ọ̀kan ní òsì rẹ̀.+