Gálátíà 4:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Àmọ́ Jerúsálẹ́mù ti òkè ní òmìnira, òun sì ni ìyá wa. 27 Nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé: “Máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ìwọ àgàn tí kò bímọ; bú sígbe ayọ̀, ìwọ obìnrin tí kò ní ìrora ìbímọ; nítorí àwọn ọmọ obìnrin tó ti di ahoro pọ̀ ju ti obìnrin tó ní ọkọ lọ.”+
26 Àmọ́ Jerúsálẹ́mù ti òkè ní òmìnira, òun sì ni ìyá wa. 27 Nítorí ó wà lákọsílẹ̀ pé: “Máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀, ìwọ àgàn tí kò bímọ; bú sígbe ayọ̀, ìwọ obìnrin tí kò ní ìrora ìbímọ; nítorí àwọn ọmọ obìnrin tó ti di ahoro pọ̀ ju ti obìnrin tó ní ọkọ lọ.”+