-
2 Kíróníkà 26:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Níkẹyìn, Ùsáyà sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, àmọ́ pápá ìsìnkú tó wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ ibi tí wọ́n ń sin àwọn ọba sí ni wọ́n sin ín sí, torí wọ́n sọ pé: “Adẹ́tẹ̀ ni.” Jótámù+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.
-