Ìsíkíẹ́lì 16:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “‘Nígbà tí mò ń kọjá lọ tí mo rí ọ, mo rí i pé o ti dàgbà tó ẹni tí wọ́n ń kọnu ìfẹ́ sí. Mo wá fi aṣọ* mi bò ọ́,+ mo fi bo ìhòòhò rẹ, mo búra, mo sì bá ọ dá májẹ̀mú,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘o sì di tèmi. Hósíà 2:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ní ọjọ́ yẹn,’ ni Jèhófà wí,‘Ọkọ Mi ni wàá máa pè mí, o ò ní pè mí ní Ọ̀gá Mi* mọ́.’
8 “‘Nígbà tí mò ń kọjá lọ tí mo rí ọ, mo rí i pé o ti dàgbà tó ẹni tí wọ́n ń kọnu ìfẹ́ sí. Mo wá fi aṣọ* mi bò ọ́,+ mo fi bo ìhòòhò rẹ, mo búra, mo sì bá ọ dá májẹ̀mú,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí, ‘o sì di tèmi.