- 
	                        
            
            Àìsáyà 51:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        6 Ẹ gbé ojú yín sókè sí ọ̀run, Kí ẹ sì wo ayé nísàlẹ̀. Torí pé ọ̀run máa fẹ́ lọ bí èéfín; Ayé máa gbó bí aṣọ, Àwọn tó ń gbé ibẹ̀ sì máa kú bíi kòkòrò abìyẹ́ tó ń mùjẹ̀. 
 
-