-
Ìfihàn 21:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 A fi oríṣiríṣi òkúta iyebíye ṣe àwọn ìpìlẹ̀ ògiri ìlú náà lọ́ṣọ̀ọ́: ìpìlẹ̀ àkọ́kọ́ jẹ́ jásípérì, ìkejì jẹ́ sàfáyà, ìkẹta jẹ́ kásídónì, ìkẹrin jẹ́ ẹ́mírádì,
-