Ìfihàn 15:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Èéfín sì kún ibi mímọ́ torí ògo Ọlọ́run+ àti agbára rẹ̀, ẹnì kankan ò sì lè wọnú ibi mímọ́ náà títí tí ìyọnu méje+ àwọn áńgẹ́lì méje náà fi parí.
8 Èéfín sì kún ibi mímọ́ torí ògo Ọlọ́run+ àti agbára rẹ̀, ẹnì kankan ò sì lè wọnú ibi mímọ́ náà títí tí ìyọnu méje+ àwọn áńgẹ́lì méje náà fi parí.