Ìfihàn 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 àti látọ̀dọ̀ Jésù Kristi, “Ẹlẹ́rìí Olóòótọ́,”+ “àkọ́bí nínú àwọn òkú,”+ àti “Alákòóso àwọn ọba ayé.”+ Ẹni tó nífẹ̀ẹ́ wa,+ tó fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ dá wa sílẹ̀ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+— Ìfihàn 3:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Laodíkíà+ pé: Àwọn ohun tí Àmín+ sọ nìyí, ẹlẹ́rìí+ olóòótọ́ tó sì ṣeé gbára lé,+ ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ohun tí Ọlọ́run dá:+
5 àti látọ̀dọ̀ Jésù Kristi, “Ẹlẹ́rìí Olóòótọ́,”+ “àkọ́bí nínú àwọn òkú,”+ àti “Alákòóso àwọn ọba ayé.”+ Ẹni tó nífẹ̀ẹ́ wa,+ tó fi ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ dá wa sílẹ̀ nínú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+—
14 “Kọ̀wé sí áńgẹ́lì ìjọ ní Laodíkíà+ pé: Àwọn ohun tí Àmín+ sọ nìyí, ẹlẹ́rìí+ olóòótọ́ tó sì ṣeé gbára lé,+ ìbẹ̀rẹ̀ àwọn ohun tí Ọlọ́run dá:+