Nọ́ńbà 14:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 ‘Jèhófà, Ọlọ́run tí kì í tètè bínú, tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀*+ sì pọ̀ gan-an, tó ń dárí ìṣìnà àti ẹ̀ṣẹ̀ jini, àmọ́ tí kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹlẹ́ṣẹ̀, tó ń fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ àwọn bàbá jẹ àwọn ọmọ, dórí ìran kẹta àti dórí ìran kẹrin.’+ Sáàmù 103:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Bí yíyọ oòrùn ṣe jìnnà sí wíwọ̀ oòrùn,Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe mú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jìnnà sí wa.+ 13 Bí bàbá ṣe ń ṣàánú àwọn ọmọ rẹ̀,Bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà ń ṣàánú àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀.+ Àìsáyà 43:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Èmi, àní èmi ni Ẹni tó ń nu àwọn àṣìṣe* rẹ+ kúrò nítorí tèmi,+Mi ò sì ní rántí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ rẹ.+
18 ‘Jèhófà, Ọlọ́run tí kì í tètè bínú, tí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀*+ sì pọ̀ gan-an, tó ń dárí ìṣìnà àti ẹ̀ṣẹ̀ jini, àmọ́ tí kò ní ṣàìfi ìyà jẹ ẹlẹ́ṣẹ̀, tó ń fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ àwọn bàbá jẹ àwọn ọmọ, dórí ìran kẹta àti dórí ìran kẹrin.’+
12 Bí yíyọ oòrùn ṣe jìnnà sí wíwọ̀ oòrùn,Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe mú àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa jìnnà sí wa.+ 13 Bí bàbá ṣe ń ṣàánú àwọn ọmọ rẹ̀,Bẹ́ẹ̀ ni Jèhófà ń ṣàánú àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀.+