Ìfihàn 8:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àmọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, áńgẹ́lì náà mú àwo tùràrí náà, ó kó díẹ̀ lára iná pẹpẹ sínú rẹ̀, ó sì jù ú sí ayé. Ààrá sán, a gbọ́ ohùn, mànàmáná kọ yẹ̀rì,+ ìmìtìtì ilẹ̀ sì wáyé.
5 Àmọ́ lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, áńgẹ́lì náà mú àwo tùràrí náà, ó kó díẹ̀ lára iná pẹpẹ sínú rẹ̀, ó sì jù ú sí ayé. Ààrá sán, a gbọ́ ohùn, mànàmáná kọ yẹ̀rì,+ ìmìtìtì ilẹ̀ sì wáyé.