Àìsáyà 1:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Torí àwọn igi ńlá tó wù yín máa tì wọ́n lójú,+Ojú sì máa tì yín torí àwọn ọgbà* tí ẹ yàn.+