Sáàmù 110:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn èèyàn rẹ máa yọ̀ǹda ara wọn tinútinú ní ọjọ́ ìjáde ogun rẹ.* Nínú ọlá ńlá ìjẹ́mímọ́, láti ibi tí ọ̀yẹ̀ ti ń là,*O ní àwùjọ àwọn ọ̀dọ́ tí wọ́n rí bí ìrì tó ń sẹ̀. Mátíù 4:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ máa tẹ̀ lé mi, màá sì sọ yín di apẹja èèyàn.”+ 20 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, wọ́n pa àwọ̀n wọn tì, wọ́n sì tẹ̀ lé e.+
3 Àwọn èèyàn rẹ máa yọ̀ǹda ara wọn tinútinú ní ọjọ́ ìjáde ogun rẹ.* Nínú ọlá ńlá ìjẹ́mímọ́, láti ibi tí ọ̀yẹ̀ ti ń là,*O ní àwùjọ àwọn ọ̀dọ́ tí wọ́n rí bí ìrì tó ń sẹ̀.
19 Ó sọ fún wọn pé: “Ẹ máa tẹ̀ lé mi, màá sì sọ yín di apẹja èèyàn.”+ 20 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, wọ́n pa àwọ̀n wọn tì, wọ́n sì tẹ̀ lé e.+