ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 2:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 ‘Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti ṣẹ́ àjàgà rẹ sí wẹ́wẹ́+

      Mo sì já ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ rẹ.

      Ṣùgbọ́n, o sọ pé: “Mi ò ní sìn ọ́,”

      Torí pé orí gbogbo òkè àti abẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀+

      Ni o nà gbalaja sí, tí ò ń ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+

  • Ìsíkíẹ́lì 16:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 O mú lára àwọn ẹ̀wù rẹ, o sì ṣe àwọn ibi gíga aláràbarà tí o ti ń ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+ Kò yẹ kí irú nǹkan bẹ́ẹ̀ wáyé, kò tiẹ̀ yẹ kó ṣẹlẹ̀ rárá.

  • Ìsíkíẹ́lì 23:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Torí náà, àwọn ọmọ Bábílónì ń wá sórí ibùsùn tó ti ń ṣeré ìfẹ́, wọ́n sì fi ìṣekúṣe wọn sọ ọ́ di ẹlẹ́gbin. Lẹ́yìn tí wọ́n sọ ọ́ di ẹlẹ́gbin, ó* kórìíra wọn, ó sì fi wọ́n sílẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́