Sáàmù 50:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nígbà tí o ṣe àwọn nǹkan yìí, mi ò sọ̀rọ̀,Torí náà, o rò pé màá dà bíi tìẹ. Àmọ́ ní báyìí, màá bá ọ wí,Màá sì pè ọ́ lẹ́jọ́.+
21 Nígbà tí o ṣe àwọn nǹkan yìí, mi ò sọ̀rọ̀,Torí náà, o rò pé màá dà bíi tìẹ. Àmọ́ ní báyìí, màá bá ọ wí,Màá sì pè ọ́ lẹ́jọ́.+