Ìsíkíẹ́lì 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ ilé Ísírẹ́lì ò ní tẹ́tí sí ọ torí wọn ò fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi.+ Olórí kunkun àti ọlọ́kàn líle ni gbogbo ilé Ísírẹ́lì.+
7 Àmọ́ ilé Ísírẹ́lì ò ní tẹ́tí sí ọ torí wọn ò fẹ́ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi.+ Olórí kunkun àti ọlọ́kàn líle ni gbogbo ilé Ísírẹ́lì.+