Jeremáyà 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ta ló yẹ kí n bá sọ̀rọ̀, kí n sì kìlọ̀ fún? Ta ló máa gbọ́? Wò ó! Etí wọn ti di,* tí wọn kò fi lè fetí sílẹ̀.+ Wò ó! Ọ̀rọ̀ Jèhófà ti di ohun tí wọ́n fi ń ṣe ẹlẹ́yà;+Inú wọn ò sì dùn sí ọ̀rọ̀ rẹ̀. Jòhánù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń hùwà burúkú kórìíra ìmọ́lẹ̀, kì í sì í wá sínú ìmọ́lẹ̀, kí a má bàa dá àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́bi.*
10 “Ta ló yẹ kí n bá sọ̀rọ̀, kí n sì kìlọ̀ fún? Ta ló máa gbọ́? Wò ó! Etí wọn ti di,* tí wọn kò fi lè fetí sílẹ̀.+ Wò ó! Ọ̀rọ̀ Jèhófà ti di ohun tí wọ́n fi ń ṣe ẹlẹ́yà;+Inú wọn ò sì dùn sí ọ̀rọ̀ rẹ̀.
20 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń hùwà burúkú kórìíra ìmọ́lẹ̀, kì í sì í wá sínú ìmọ́lẹ̀, kí a má bàa dá àwọn iṣẹ́ rẹ̀ lẹ́bi.*