-
Ìsíkíẹ́lì 5:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Èyí ni Jerúsálẹ́mù. Mo ti fi í sí àárín àwọn orílẹ̀-èdè, àwọn ìlú sì yí i ká. 6 Àmọ́, ó ti kọ àwọn ìdájọ́ àti àṣẹ mi, ìwà rẹ̀ sì burú ju ti àwọn orílẹ̀-èdè àti àwọn ìlú tó yí i ká lọ.+ Torí wọ́n ti kọ àwọn ìdájọ́ mi, wọn ò sì tẹ̀ lé àwọn àṣẹ mi.’
-