Éfésù 6:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bákan náà, ẹ gba akoto* ìgbàlà+ àti idà ẹ̀mí, ìyẹn, ọ̀rọ̀ Ọlọ́run,+ 1 Tẹsalóníkà 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ ní ti àwa tí a jẹ́ ti ọ̀sán, ẹ jẹ́ kí a máa ronú bó ṣe tọ́, kí a gbé àwo ìgbàyà ìgbàgbọ́ àti ìfẹ́ wọ̀, kí a sì dé ìrètí ìgbàlà bí akoto*+
8 Àmọ́ ní ti àwa tí a jẹ́ ti ọ̀sán, ẹ jẹ́ kí a máa ronú bó ṣe tọ́, kí a gbé àwo ìgbàyà ìgbàgbọ́ àti ìfẹ́ wọ̀, kí a sì dé ìrètí ìgbàlà bí akoto*+