Àìsáyà 62:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé: “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+ Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+
11 Ẹ wò ó! Jèhófà ti kéde títí dé àwọn ìkángun ayé pé: “Ẹ sọ fún ọmọbìnrin Síónì pé,‘Wò ó! Ìgbàlà rẹ ń bọ̀.+ Wò ó! Èrè rẹ̀ wà pẹ̀lú rẹ̀,Ẹ̀san rẹ̀ sì wà níwájú rẹ̀.’”+