Ìfihàn 21:23, 24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ìlú náà ò nílò kí oòrùn tàbí òṣùpá tàn sórí rẹ̀, torí ògo Ọlọ́run mú kó mọ́lẹ̀ rekete,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì ni fìtílà rẹ̀.+ 24 Àwọn orílẹ̀-èdè máa rìn nínú ìmọ́lẹ̀ rẹ̀,+ àwọn ọba ayé sì máa mú ògo wọn wá sínú rẹ̀.
23 Ìlú náà ò nílò kí oòrùn tàbí òṣùpá tàn sórí rẹ̀, torí ògo Ọlọ́run mú kó mọ́lẹ̀ rekete,+ Ọ̀dọ́ Àgùntàn náà sì ni fìtílà rẹ̀.+ 24 Àwọn orílẹ̀-èdè máa rìn nínú ìmọ́lẹ̀ rẹ̀,+ àwọn ọba ayé sì máa mú ògo wọn wá sínú rẹ̀.