- 
	                        
            
            2 Àwọn Ọba 16:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        5 Ìgbà náà ni Résínì ọba Síríà àti Pékà ọmọ Remaláyà ọba Ísírẹ́lì wá gbógun ja Jerúsálẹ́mù.+ Wọ́n dó ti Áhásì, àmọ́ wọn ò rí ìlú náà gbà. 
 
-