Sekaráyà 8:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ẹ̀yin ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì, bí ẹ ṣe di ẹni ègún láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ bẹ́ẹ̀ náà ni èmi yóò gbà yín là, ẹ ó sì di ẹni ìbùkún.+ Ẹ má bẹ̀rù!+ Ẹ jẹ́ onígboyà.’*+
13 Ẹ̀yin ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì, bí ẹ ṣe di ẹni ègún láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ bẹ́ẹ̀ náà ni èmi yóò gbà yín là, ẹ ó sì di ẹni ìbùkún.+ Ẹ má bẹ̀rù!+ Ẹ jẹ́ onígboyà.’*+