Sáàmù 149:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí inú Jèhófà ń dùn sí àwọn èèyàn rẹ̀.+ Ó ń fi ìgbàlà ṣe àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ lọ́ṣọ̀ọ́.+ Sefanáyà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà ní àárín rẹ.+ Ó máa gbani là bí Alágbára ńlá. Ó máa yọ̀ gidigidi nítorí rẹ.+ Á dákẹ́ jẹ́ẹ́* nínú ìfẹ́ rẹ̀. Á dunnú nítorí rẹ pẹ̀lú igbe ayọ̀.
17 Jèhófà Ọlọ́run rẹ wà ní àárín rẹ.+ Ó máa gbani là bí Alágbára ńlá. Ó máa yọ̀ gidigidi nítorí rẹ.+ Á dákẹ́ jẹ́ẹ́* nínú ìfẹ́ rẹ̀. Á dunnú nítorí rẹ pẹ̀lú igbe ayọ̀.