Ìṣe 7:51 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+ Éfésù 4:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Bákan náà, ẹ má ṣe máa kó ẹ̀dùn ọkàn* bá ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run,+ èyí tí a fi gbé èdìdì lé+ yín fún ọjọ́ ìtúsílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà.+
51 “Ẹ̀yin olóríkunkun àti aláìkọlà* ọkàn àti etí, gbogbo ìgbà lẹ̀ ń ta ko ẹ̀mí mímọ́; bí àwọn baba ńlá yín ti ṣe náà lẹ̀ ń ṣe.+
30 Bákan náà, ẹ má ṣe máa kó ẹ̀dùn ọkàn* bá ẹ̀mí mímọ́ Ọlọ́run,+ èyí tí a fi gbé èdìdì lé+ yín fún ọjọ́ ìtúsílẹ̀ nípasẹ̀ ìràpadà.+