Sáàmù 77:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 O darí àwọn èèyàn rẹ bí agbo ẹran,+Lábẹ́ àbójútó* Mósè àti Áárónì.+