Àìsáyà 41:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Má bẹ̀rù, ìwọ Jékọ́bù kòkòrò mùkúlú,*+Ẹ̀yin ọkùnrin Ísírẹ́lì, màá ràn yín lọ́wọ́,” ni Jèhófà, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì wí.
14 Má bẹ̀rù, ìwọ Jékọ́bù kòkòrò mùkúlú,*+Ẹ̀yin ọkùnrin Ísírẹ́lì, màá ràn yín lọ́wọ́,” ni Jèhófà, Olùtúnrà yín,+ Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì wí.