-
Sáàmù 74:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Rántí Òkè Síónì, ibi tí o gbé.+
-
-
Sáàmù 80:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, jọ̀wọ́ pa dà.
Bojú wolẹ̀ láti ọ̀run, kí o sì rí i!
-