Hábákúkù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó dúró jẹ́ẹ́, ó sì mi ayé jìgìjìgì.+ Ó wo àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì mú kí wọ́n gbọ̀n rìrì.+ Ó fọ́ àwọn òkè tó ti wà tipẹ́,Àwọn òkè àtayébáyé sì tẹrí ba.+ Òun ló ni àwọn ọ̀nà àtijọ́.
6 Ó dúró jẹ́ẹ́, ó sì mi ayé jìgìjìgì.+ Ó wo àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì mú kí wọ́n gbọ̀n rìrì.+ Ó fọ́ àwọn òkè tó ti wà tipẹ́,Àwọn òkè àtayébáyé sì tẹrí ba.+ Òun ló ni àwọn ọ̀nà àtijọ́.