Róòmù 10:20, 21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ Àìsáyà fi ìgboyà sọ̀rọ̀, ó ní: “Àwọn tí kò wá mi ti rí mi,+ àwọn tí kò béèrè mi ti wá mọ̀ mí.”+ 21 Àmọ́, ó sọ nípa Ísírẹ́lì pé: “Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, mo tẹ́ ọwọ́ mi sí àwọn èèyàn tó jẹ́ aláìgbọràn àti olóríkunkun.”+
20 Àmọ́ Àìsáyà fi ìgboyà sọ̀rọ̀, ó ní: “Àwọn tí kò wá mi ti rí mi,+ àwọn tí kò béèrè mi ti wá mọ̀ mí.”+ 21 Àmọ́, ó sọ nípa Ísírẹ́lì pé: “Láti àárọ̀ ṣúlẹ̀, mo tẹ́ ọwọ́ mi sí àwọn èèyàn tó jẹ́ aláìgbọràn àti olóríkunkun.”+