Àìsáyà 66:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbọ̀n rìrì* torí ọ̀rọ̀ rẹ̀: “Àwọn arákùnrin yín tó kórìíra yín, tí wọ́n sì ta yín nù nítorí orúkọ mi sọ pé, ‘Ká yin Jèhófà lógo!’+ Àmọ́ Ó máa fara hàn, ó sì máa mú ayọ̀ wá fún yín,Àwọn sì ni ojú máa tì.”+
5 Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbọ̀n rìrì* torí ọ̀rọ̀ rẹ̀: “Àwọn arákùnrin yín tó kórìíra yín, tí wọ́n sì ta yín nù nítorí orúkọ mi sọ pé, ‘Ká yin Jèhófà lógo!’+ Àmọ́ Ó máa fara hàn, ó sì máa mú ayọ̀ wá fún yín,Àwọn sì ni ojú máa tì.”+