Àìsáyà 30:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Ó yá, lọ, kọ ọ́ sára wàláà níṣojú wọn,Kí o sì kọ ọ́ sínú ìwé,+Kó lè wúlò lọ́jọ́ ọ̀la,Láti jẹ́ ẹ̀rí tó máa wà títí láé.+
8 “Ó yá, lọ, kọ ọ́ sára wàláà níṣojú wọn,Kí o sì kọ ọ́ sínú ìwé,+Kó lè wúlò lọ́jọ́ ọ̀la,Láti jẹ́ ẹ̀rí tó máa wà títí láé.+