Mátíù 5:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé: Má ṣe búra rárá,+ ì báà jẹ́ ọ̀run lo fi búra, torí ìtẹ́ Ọlọ́run ni; 35 tàbí ayé, torí àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀ ni;+ tàbí Jerúsálẹ́mù, torí ìlú Ọba ńlá náà ni.+
34 Àmọ́ mò ń sọ fún yín pé: Má ṣe búra rárá,+ ì báà jẹ́ ọ̀run lo fi búra, torí ìtẹ́ Ọlọ́run ni; 35 tàbí ayé, torí àpótí ìtìsẹ̀ rẹ̀ ni;+ tàbí Jerúsálẹ́mù, torí ìlú Ọba ńlá náà ni.+